bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Ezekiel 30
Ezekiel 30
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 29
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 31 →
1
Ọ̀rọ̀ OLÚWA tún tọ̀ mí wá: wí pé:
2
“Ọmọ ènìyàn, ṣọtẹ́lẹ̀ kí o sì wí pé: ‘Báyìí ní OLÚWA Ọlọ́run wí: “ ‘Pohùnréré ẹkún kí o sì wí pé, “Ó ṣe fún ọjọ́ náà!”
3
Nítorí ọjọ́ náà sún mọ́ tòsí àní ọjọ́ OLÚWA sún mọ́ tòsí Ọjọ́ tí ọjọ́ ìkùukùu ṣú dúdú, àsìkò ìparun fún àwọn aláìkọlà
4
Idà yóò wá sórí Éjíbítì ìrora ńlá yóò sì wá sórí Kúṣì Nígbà tí àwọn tí a pa yóò subú ní Éjíbítì wọn yóò kò ọrọ̀ rẹ̀ lọ ìpìlẹ̀ rẹ̀ yóò sì wó lulẹ̀.
5
Kúṣì àti Pútì, Lídíà àti gbogbo Árábù, Líbíyà àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ ìlérí yóò ṣubú nípa idà papọ̀ pẹ̀lú Éjíbítì.
6
“ ‘Èyí yìí ní OLÚWA wí: “ ‘Àwọn alejò Éjíbítì yóò ṣubú agbára ìgbéraga rẹ yóò kùnà láti Mígídólì títí dé Ásúwánì wọn yóò ti ipa idà ṣubú láàárin rẹ; ní OLÚWA Ọlọ́run wí:
7
Wọn yóò sì wà lára àwọn ilẹ̀ tí ó di ahoro, ìlú rẹ yóò sì wà ní ara àwọn ìlú tí ó di ahoro.
8
Lẹ́yìn náà wọn yóò mọ̀ pé èmi ní OLÚWA, nígbà tí mo bá gbé iná kalẹ̀ ní Ijíbítì tí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá parun.
9
“ ‘Ní ọjọ́ náà oníṣẹ́ yóò ti ọ̀dọ̀ mi jáde nínú ọkọ̀ ojú omi láti dẹ́rùbà Kúsì kúrò nínú ìtẹ́lọ́rùn rẹ̀. Ìrora yóò wá sórí wọn gẹ́gẹ́ bí ti ọjọ́ ìparun Éjíbítì: Kíyèsí i, ó dé.
10
“ ‘Báyìí ni OLÚWA Ọlọ́run wí: “ ‘Èmi yóò mú òpin bá ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn Éjíbítì láti ọwọ́ Nébukadinésárì ọba Bábílónì.
11
Òun àti àwọn ológun rẹ̀ ẹ́rù àwọn orílẹ̀-èdè ní a o mú wá láti pa ilẹ náà run. Wọn yóò fa idà wọn yọ sí Éjíbítì ilẹ̀ náà yóò sì kún fún àwọn tí a pa.
12
Èmi yóò mú kí àwọn odò Náílì gbẹ Èmi yóò sì ta ilẹ náà fún àwọn ènìyàn búburú: láti ọwọ́ àwọn àjòjì ènìyàn Èmi yóò jẹ́ kí ilẹ̀ náà àti gbogbo ohun tí ó wá nínú rẹ ṣòfò. Èmi OLÚWA ni ó ti sọ ọ́.
13
“ ‘Báyìí ní OLÚWA Ọlọ́run wí: “ ‘Èmi yóò pa àwọn òrìṣà run Èmi yóò sì mú kí òpin dé bá ère òrìṣà gbígbẹ́ ni Nófì kò ní sí ọmọ aládé mọ́ ní Éjíbítì, Èmi yóò mú kí ìbẹ̀rù gba gbogbo ilẹ̀ náà.
14
Èmi yóò sì mú kí Pátírọ́sì di ahoro èmi yóò fi ina sí Sóánì èmi yóò sì fi ìyà jẹ Tébésì
15
Èmi yóò tú ìbínú mi jáde sórí Pélúsíómù ìlú odi Éjíbítì èmi yóò sì ké àkójọpọ̀ Jépésì kúrò
16
Èmi yóò ti iná bọ Éjíbítì Pélúsíómù yóò japoró ní ìrora Èfúùfù yóò jà ní Tébésì Mémìfísì yóò wà ìpọ́njú ní ìgbà gbogbo
17
Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ní Hẹ́lópónísè àti Búbásítì yóò ti ipa idà subú wọn yóò sì kó àwọn ìlú wọn ní ìgbèkùn
18
Ojú ọjọ́ yóò ṣókùnkùn ní Tápárebì nígbà tí mo bá já àjàgà Éjíbítì kúrò; níbẹ̀ agbára iyì rẹ̀ yóò dópin wọn yóò fi ìkùukùu bò ó àwọn abúlé rẹ ní wọn yóò lọ sí ìgbèkùn.
19
Nítorí náà Èmi yóò mú ki ìjìyà wá sórí Éjíbítì, wọn yóò sì mọ̀ pé Èmi ni OLÚWA.’ ”
20
Ní ọjọ́ keje osù kìn-ín-ní ọdún kọkànlá ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ̀ mí wá:
21
“Ọmọ ènìyàn, Èmi ti ṣe apa Fáráò Ọba Éjíbítì. A kò ì tí ì di apá náà papọ̀ láti mu kí ó san, a ko sì ti di i si àárin igi pẹlẹbẹ kí o lè ni agbára tó láti di idà mú.
22
Nítorí náà, báyìí ní OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: Èmi lòdì sí Fáráò Ọba Éjíbítì. Èmi yóò sẹ́ apá rẹ̀ méjèèjì, èyí tí ó dára àti èyí tí a ti ṣẹ́ pẹ̀lú, yóò sì mú kí idà bọ́ sọnù ní ọwọ́ rẹ̀.
23
Èmi yóò sì fọ́n àwọn ènìyàn Éjíbítì ká sí àárin àwọn orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká gbogbo ilẹ̀.
24
Èmi yóò mú kí apá Ọba Bábílónì ní agbára, èmi yóò sì fi idà mi sí ọwọ́ rẹ, ṣùgbọ́n èmi yóò ṣẹ́ apá Fáráò, yóò sì kérora níwájú rẹ̀ bí ọkùnrin tí a ṣá ní àṣápa.
25
Èmi yóò mú kí apá Ọba Bábílónì lé, ṣùgbọ́n apá Fáráò yóò sì rọ. Nígbà náà wọn yóò mọ̀ pé Èmi ni OLÚWA, nígbà tí mo bá mú idà mi sí ọwọ́ Ọba Bábílónì yóò sì fí idà náà kọlu Éjíbítì.
26
Èmi yóò fọ́n àwọn ara Éjíbítì ká sí àárin orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká sí àárin orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká sí gbogbo ilẹ̀. Nígbà náà wọn yóò mọ̀ pé èmi ni OLÚWA.”
← Chapter 29
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 31 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48