bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba 2010
/
Isaiah 2
Isaiah 2
Yoruba 2010
← Chapter 1
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 49
Chapter 50
Chapter 51
Chapter 52
Chapter 53
Chapter 54
Chapter 55
Chapter 56
Chapter 57
Chapter 58
Chapter 59
Chapter 60
Chapter 61
Chapter 62
Chapter 63
Chapter 64
Chapter 65
Chapter 66
Chapter 3 →
1
Ọ̀rọ̀ tí Aisaya ọmọ Amosi sọ nípa Juda ati Jerusalẹmu nìyí:
2
Ní ọjọ́ iwájú òkè ilé OLUWA yóo fi ìdí múlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òkè tí ó ga jùlọ, a óo sì gbé e ga ju àwọn òkè yòókù lọ. Gbogbo orílẹ̀-èdè yóo wá sibẹ.
3
Ọpọlọpọ eniyan ni yóo wá, tí wọn yóo máa wí pé: “Ẹ wá! Ẹ jẹ́ kí á gun òkè OLUWA lọ, kí á lọ sí ilé Ọlọrun Jakọbu, kí ó lè kọ́ wa ní ìlànà rẹ̀, kí á sì lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀. Nítorí pé láti Sioni ni òfin Ọlọrun yóo ti jáde wá ọ̀rọ̀ OLUWA yóo sì wá láti Jerusalẹmu.”
4
Yóo ṣe ìdájọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; yóo sì bá ọpọlọpọ eniyan wí. Wọn yóo fi idà wọn rọ ọkọ́, wọn yóo sì fi ọ̀kọ̀ wọn rọ dòjé. Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́, wọn kò sì ní kọ́ ogun jíjà mọ́.
5
Ẹ̀yin ìdílé Jakọbu ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á rìn ninu ìmọ́lẹ̀ OLUWA.
6
Nítorí o ti ta àwọn eniyan rẹ nù, àní, ìdílé Jakọbu. Nítorí pé àwọn aláfọ̀ṣẹ ará ìhà ìlà oòrùn pọ̀ láàrin wọn, àwọn alásọtẹ́lẹ̀ sì pọ̀ bíi ti àwọn ará Filistini, Wọ́n ti gba àṣà àwọn àjèjì.
7
Wúrà ati fadaka kún ilẹ̀ wọn, ìṣúra wọn kò sì lópin. Ẹṣin kún ilẹ̀ wọn, kẹ̀kẹ́ ogun wọn kò sì lóǹkà.
8
Ilẹ̀ wọn kún fún oriṣa, wọ́n ń bọ iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn, wọ́n ń wólẹ̀ fún ohun tí wọ́n fọwọ́ ara wọn ṣe.
9
Bẹ́ẹ̀ ni eniyan ṣe tẹ ara rẹ̀ lórí ba tí ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀. Oluwa, máṣe dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n.
10
Ẹ wọnú àpáta lọ, kí ẹ sì farapamọ́ sinu ilẹ̀. Ẹ sá fún ibinu OLUWA ati ògo ọlá ńlá rẹ̀.
11
A óo rẹ ọlọ́kàn gíga eniyan sílẹ̀, a óo sì rẹ àwọn onigbeeraga sílẹ̀; OLUWA nìkan ni a óo gbéga ní ọjọ́ náà.
12
Nítorí OLUWA àwọn ọmọ ogun ti ya ọjọ́ kan sọ́tọ̀, tí yóo dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, ati àwọn ọlọ́kàn gíga, ati gbogbo nǹkan tí à ń gbéga.
13
Yóo dojú kọ gbogbo igi Kedari ti Lẹbanoni, tí ó ga fíofío, ati gbogbo igi oaku ilẹ̀ Baṣani;
14
ati gbogbo àwọn òkè ńláńlá, ati gbogbo òkè gíga,
15
ati gbogbo ilé-ìṣọ́ gíga ati gbogbo odi tí ó lágbára,
16
ati gbogbo ọkọ̀ ojú omi láti ìlú Taṣiṣi, ati gbogbo ọkọ̀ tí ó dára.
17
Àwọn ọlọ́kàn gíga yóo di ẹni ilẹ̀, a óo sì rẹ àwọn onigbeeraga sílẹ̀. OLUWA nìkan ni a óo gbéga ní ọjọ́ náà,
18
àwọn oriṣa yóo sì pòórá patapata.
19
Àwọn eniyan yóo sá sinu ihò àpáta, wọn yóo sì wọ inú ihò ilẹ̀ lọ, nígbà tí wọ́n bá ń sá fún ibinu OLUWA, ati ògo ọlá ńlá rẹ̀ nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.
20
Ní ọjọ́ náà, àwọn eniyan óo kó àwọn ère fadaka wọn dànù, ati àwọn ère wúrà tí wọ́n fi ọwọ́ ara wọn ṣe, tí wọn tún ń bọ. Wọn yóo dà wọ́n fún àwọn èkúté ati àwọn àdán.
21
Wọn óo wọ inú pàlàpálá àpáta, ati inú ihò àwọn òkè gíga; nígbà tí wọn bá ń sá fún ibinu OLUWA, ati ògo ọlá ńlá rẹ̀, nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.
22
Ẹ má gbẹ́kẹ̀lé eniyan mọ́. Ẹlẹ́mìí ni òun alára, nítorí pé kí ni ó lè ṣe?
← Chapter 1
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 49
Chapter 50
Chapter 51
Chapter 52
Chapter 53
Chapter 54
Chapter 55
Chapter 56
Chapter 57
Chapter 58
Chapter 59
Chapter 60
Chapter 61
Chapter 62
Chapter 63
Chapter 64
Chapter 65
Chapter 66
Chapter 3 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66