bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba 2010
/
Isaiah 21
Isaiah 21
Yoruba 2010
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 49
Chapter 50
Chapter 51
Chapter 52
Chapter 53
Chapter 54
Chapter 55
Chapter 56
Chapter 57
Chapter 58
Chapter 59
Chapter 60
Chapter 61
Chapter 62
Chapter 63
Chapter 64
Chapter 65
Chapter 66
Chapter 22 →
1
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa aṣálẹ̀ etí òkun nìyí: àjálù kan ń já bọ̀ láti inú aṣálẹ̀, láti ilẹ̀ tí ó bani lẹ́rù, ó ń bọ̀ bí ìjì líle tí ń jà bọ̀ láti ìhà àríwá aṣálẹ̀.
2
Ìran tí a fi hàn mí yìí le: Àwọn oníjàgídíjàgan lọ digun kó ìkógun, abanǹkanjẹ́ sì ba nǹkan jẹ́. Ẹ̀yin ará Elamu, ẹ gòkè lọ! Ẹ̀yin ará Media, ẹ múra ogun! Mo ti fòpin sí òṣé ati ìjìyà tí Babiloni kó bá gbogbo eniyan.
3
Nítorí náà, gbogbo ẹ̀gbẹ́ ní ń dùn mí, gbogbo ara ní ń ro mí bí obinrin tí ń rọbí lọ́wọ́. A tẹrí mi ba kí n má baà gbọ́ nǹkankan, wọ́n dẹ́rù bà mí kí n má baà ríran.
4
Ọkàn mi dààmú, jìnnìjìnnì dà bò mí; wọ́n ti sọ àfẹ̀mọ́júmọ́ tí mò ń retí di ìbẹ̀rù mọ́ mi lọ́wọ́.
5
Wọ́n tẹ́ tabili, wọ́n sì tẹ́ aṣọ sílẹ̀ wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu. Ariwo bá ta pé “Ẹ gbéra nílẹ̀, ẹ̀yin ológun! Ẹ fepo pa asà yín.”
6
Nítorí OLUWA wí fún mi pé: “Lọ fi aṣọ́nà ṣọ́ ojú ọ̀nà, kí ó máa kéde ohun tí ó bá rí.
7
Nígbà tí ó bá rí àwọn ẹlẹ́ṣin tí wọn ń bọ̀ ní meji-meji, bí ó bá rí i tí àwọn kan gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, tí àwọn kan gun ràkúnmí, kí ó fara balẹ̀ dáradára, kí ó dẹtísílẹ̀ dáradára.”
8
Ẹni tí ń ṣọ́nà kígbe pé: “OLUWA mi, lórí ilé-ìṣọ́ ni èmi í dúró sí lojoojumọ, níbi tí a fi mí ṣọ́, ni èmi í sì í wà ní òròòru.
9
Ẹ wò ó! Àwọn ẹlẹ́ṣin kan ń bọ̀, wọ́n fẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́ ní meji-meji!” “Ẹ gbọ́! Ìlú Babiloni ti wó! Ó ti wó! Pẹlu gbogbo àwọn oriṣa rẹ̀, ó ti wó lulẹ̀ patapata.”
10
Ẹ̀yin eniyan mi tí a ti tẹ̀ mọ́lẹ̀, bí ẹni tẹ ọkà ní ibi ìpakà, ohun tí mo gbọ́ láti ọ̀dọ̀ OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli, ní mò ń kéde fun yín yìí.
11
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Edomu nìyí: Ẹnìkan ń pè mí láti Seiri Ó ní: “Aṣọ́nà, Òru ti rí o? Aṣọ́nà, àní òru ti rí?”
12
Aṣọ́nà bá dáhùn, ó ní: “Ilẹ̀ ń ṣú, ilẹ̀ sì ń mọ́. Bí ẹ bá tún fẹ́ bèèrè, ẹ pada wá, kí ẹ tún wá bèèrè.”
13
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Arabia nìyí: Ninu igbó Arabia ni ẹ óo sùn, ẹ̀yin èrò ará Didani.
14
Ẹ bu omi wá fún ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ. Ẹ gbé oúnjẹ pàdé ẹni tí ń sá fógun, ẹ̀yin ará ilẹ̀ Tema.
15
Wọ́n ń sá fún idà, wọ́n sá fún idà lójú ogun. Wọ́n ń sá fún àwọn tafàtafà, wọ́n sá fún líle ogun.
16
OLUWA sọ fún mi pé, “Kí ó tó tó ọdún kan, ní ìwọ̀n ọdún alágbàṣe kan, gbogbo ògo Kedari yóo dópin;
17
díẹ̀ ni yóo sì kù ninu àwọn tafàtafà alágbára ọmọ Kedari; nítorí OLUWA Ọlọrun Israẹli ló sọ bẹ́ẹ̀.”
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 43
Chapter 44
Chapter 45
Chapter 46
Chapter 47
Chapter 48
Chapter 49
Chapter 50
Chapter 51
Chapter 52
Chapter 53
Chapter 54
Chapter 55
Chapter 56
Chapter 57
Chapter 58
Chapter 59
Chapter 60
Chapter 61
Chapter 62
Chapter 63
Chapter 64
Chapter 65
Chapter 66
Chapter 22 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66