bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba 2010
/
Proverbs 21
Proverbs 21
Yoruba 2010
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 22 →
1
Orísun omi ni ọkàn ọba lọ́wọ́ OLUWA, ibi tí ó bá wu Oluwa ni ó ń darí rẹ̀ sí.
2
Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó dára lójú ara rẹ̀, ṣugbọn ọkàn ni OLUWA ń wò.
3
Kí eniyan ṣe òdodo ati ẹ̀tọ́, sàn ju ẹbọ lọ lójú OLUWA.
4
Bíi fìtílà ẹni ibi ni gbígbé ojú gangan ati ìgbéraga, ẹ̀ṣẹ̀ sì ni wọ́n.
5
Dájúdájú èrò ẹni tí ó ṣiṣẹ́ tọkàntọkàn yóo yọrí sí ọ̀pọ̀, ṣugbọn ẹni tí ó bá ń kánjú jù kò ní ní ànító.
6
Fífi èké kó ìṣúra jọ dàbí lílé ìkùukùu, ó sì jẹ́ tàkúté ikú.
7
Ìwà ipá àwọn ẹni ibi ni yóo gbá wọn dànù, nítorí pé wọ́n kọ̀ láti ṣe òtítọ́.
8
Ọ̀nà ẹlẹ́bi kì í gún, ṣugbọn ìrìn aláìlẹ́bi a máa tọ́.
9
Ó sàn láti máa gbé kọ̀rọ̀ kan lókè àjà, ju pé kí eniyan máa bá oníjàngbọ̀n obinrin gbé ilé lọ.
10
Ibi ni ọkàn eniyan burúkú máa ń fẹ́, àwọn aládùúgbò rẹ̀ kì í sìí rí ojurere rẹ̀.
11
Ìjìyà ẹlẹ́yà a máa mú kí òpè gbọ́n, tí a bá ń kọ́ ọlọ́gbọ́n, yóo ní ìmọ̀ sí i.
12
Olódodo ṣàkíyèsí ilé eniyan burúkú, eniyan burúkú sì bọ́ sinu ìparun.
13
Ẹni tí ó kọ etí dídi sí igbe talaka, òun náà yóo kígbe, ṣugbọn kò ní rí ẹni dá a lóhùn.
14
Ẹ̀bùn tí a fúnni ní kọ̀rọ̀ a máa paná ibinu, àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tí a tì bọ abẹ́ aṣọ a máa paná ìjà.
15
Tí a bá ṣe ìdájọ́ òtítọ́, inú olódodo a dùn, ṣugbọn ìfòyà ni fún àwọn aṣebi.
16
Ẹni tí ó sá kúrò lọ́nà òye yóo sinmi láàrin àwọn òkú.
17
Ẹni tí ó fẹ́ràn fàájì yóo di talaka, ẹni tí ó fẹ́ràn ọtí waini ati òróró kò ní lówó lọ́wọ́.
18
Eniyan burúkú ni yóo forí gba ibi tíì bá dé bá olódodo. Alaiṣootọ ni yóo fara gba ìyà tí ó tọ́ sí olóòótọ́ inú.
19
Ó sàn láti máa gbé ààrin aṣálẹ̀, ju kí eniyan máa bá oníjà ati oníkanra obinrin gbé lọ.
20
Ní ilé ọlọ́gbọ́n ni à á tí ń bá nǹkan olówó iyebíye, ṣugbọn òmùgọ̀ a máa ba tirẹ̀ jẹ́.
21
Ẹni tí ń lépa òdodo ati àánú yóo rí ìyè, òdodo, ati iyì.
22
Ọlọ́gbọ́n a máa gba ìlú àwọn alágbára a sì wó ibi ààbò tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé lulẹ̀.
23
Ẹni tí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́ pa ara rẹ̀ mọ́ kúrò ninu ìyọnu.
24
“Oníyẹ̀yẹ́” ni orúkọ ẹni tí ń gbéraga, tí ó sì ń ṣe mo tó báyìí-dà báyìí.
25
Ìrònú ohun tí ọ̀lẹ fẹ́ ni yóo pa á, nítorí ọwọ́ rẹ̀ kọ̀ láti ṣiṣẹ́.
26
Eniyan burúkú a máa ṣe ojúkòkòrò ní gbogbo ìgbà, ṣugbọn olódodo ń fúnni láìdáwọ́dúró.
27
Ohun ìríra ni ẹbọ eniyan burúkú, pàápàá tí ó bá mú un wá pẹlu èrò ibi.
28
Ọ̀rọ̀ ẹlẹ́rìí èké yóo di asán, ṣugbọn ọ̀rọ̀ ẹni tí ó fetí sílẹ̀ ni a óo gbàgbọ́.
29
Eniyan burúkú a máa lo ògbójú, ṣugbọn olóòótọ́ máa ń yẹ ọ̀nà ara rẹ̀ wò.
30
Kò sí ọgbọ́n, tabi òye, tabi ìmọ̀, tí ó lè dojú kọ OLUWA kí ó mókè.
31
Eniyan a máa tọ́jú ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun, ṣugbọn OLUWA ló ni ìṣẹ́gun.
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 22 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31