bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Job 17
Job 17
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 16
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 18 →
1
“Ẹ̀mí mi bàjẹ́, ọjọ́ mi ni a ti gé kúrú, ìsà òkú dúró dè mí.
2
Nítòótọ́ àwọn ẹlẹ́yà h wà lọ́dọ̀ mi, ojú mi sì tẹ̀mọ́ ìmúnibínú wọn.
3
“Ǹjẹ́ nísinsínyí, fi lélẹ̀ yàn onígbọ̀wọ́ fún mi lọ́dọ̀ rẹ; ta ni OLÚWA tí yóò le ṣe ààbò fún mi?
4
Nítorí pé ìwọ ti ṣé wọ́n láyà kúrò nínú òyè; nítorí náà ìwọ kì yóò gbé wọn lékè.
5
Ẹni tí ó fi àwọn ọ̀rẹ́ hàn fún ìgárá, òun ni ojú àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú òfo.
6
“Ọlọ́run ti sọ mi di ẹni òwe fún àwọn ènìyàn; níwájú wọn ni mo dàbí ẹni ìtutọ́ sí ní ojú.
7
Ojú mí ṣú bàìbàì nítorí ìbìnújẹ́, gbogbo ẹ̀yà ara mi sì dàbí òjìji.
8
Àwọn olódodo yóò yanu sí èyí, ẹni aláìsẹ̀ sì bínú sí àwọn àgàbàgebè.
9
Olódodo pẹ̀lú yóò di ọ̀nà rẹ̀ mú, àti ọlọ́wọ́ mímì yóò máa lera síwájú.
10
“Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti gbogbo yín, ẹ yí padà, kí ẹ sì tún bọ̀ nísinsin yìí; èmi kò le rí ọlọgbọ́n kan nínú yín.
11
Ọjọ́ tí èmi ti kọjá, ìro mi ti fà já, àní ìro ọkàn mi.
12
Àwọn ènìyàn wọn yí ìsọ́ òru di ọ̀sán; wọ́n ní, ìmọ́lẹ̀ súnmọ́ ibi tí òkùnkùn dé.
13
Bí mo tilẹ̀ ní ìrètí, ipò òku ní ilé mi; mo ti tẹ́ ìbùsùn mi sínú òkùnkùn.
14
Èmi ti wí fún ìdibàjẹ́ pé, ìwọ ni baba mi, àti fún kòkòrò pé, ìwọ ni ìyá mi àti arábìnrin mi,
15
Ìrètí mi ha dà nísinsinyí? Bí ó ṣe ti ìrètí mi ni, ta ni yóò rí i?
16
Yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sínú ipò òkú, nígbà tí a jùmọ̀ sinmi pọ̀ nínú erùpẹ̀ ilẹ̀?”
← Chapter 16
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 18 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42