bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Job 21
Job 21
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 22 →
1
Jóòbù wá dahùn, ó sì wí pé:
2
“Ẹ tẹ́tí silẹ̀ dẹdẹ sì àwọn ọ̀rẹ́ mi, kí èyí kí ó jásí ìtùnú tí ó fún mi.
3
Ẹ jọ̀wọ́ mi ki èmi sọ̀rọ̀; lẹ́yìn ìgbà tí mo bá sọ tán, ìwọ máa fi ṣẹ̀sín ń ṣo.
4
“Bí ó ṣe tí èmi ni, àròyé mi iṣe sí ènìyàn bí? Tàbí èétíṣe tí ọkàn mi kì yóò fi ṣe àìbalẹ̀?
5
Ẹ wò mí fín, kí ẹnu kí ó sì yà yín, kí ẹ sì fi ọwọ́ lé ẹnu yín.
6
Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí, ìwárìrì sì mú mi lára.
7
Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé, tí wọ́n gbó, àní tí wọ́n di alágbára ní ipa?
8
Irú ọmọ wọn fi ìdí kalẹ̀ ní ojú wọn pẹ̀lú wọn, àti ọmọ-ọmọ wọn ní ojú wọn.
9
Ilé wọn wà láìní ewu àti ẹ̀rù, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀pá iná Ọlọ́run kò sí lára wọn.
10
Akọ màlúù wọn a máa gùn, kì ísì íṣe; abo màlúù wọn a máa bí, kì í sì í ṣẹ́yun;
11
Wọn a máa rán àwọn ọmọ wọn wẹ́ẹ́wẹ́ẹ́ jáde bí agbo ẹran, àwọn ọmọ wọn a sì máa jó kiri.
12
Wọ́n mú ohun ọ̀nà orin, ìlù àti háápù, wọ́n sì ń yọ̀ sí ohùn fèrè
13
Wọ́n ní ọjọ́ wọn nínú ọrọ̀; wọn sì lọ sí ipò òkú ní àlàáfíà.
14
Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí fún Ọlọ́run pé, lọ kúrò lọ́dọ̀ wa, nítorí pé wọn kò fẹ́ ìmọ̀ ipa ọ̀nà rẹ!
15
Kí ni Olódùmarè tí àwa ó fi máa sìn in? Èrè kí ni a ó sì jẹ bí àwa ba gbàdúrà sí i?
16
Kíyè sí i, àlàáfíà wọn kò sí nípa ọwọ́ wọn; ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí ni réré.
17
“Ìgbà mélòómélòó ní a ń pa iná ènìyàn búburú kú? Ìgbà mélòómélòó ní ìparun wọn dé bá wọn, tí Ọlọ́run sì í máa pín ìbìnújẹ́ nínú ìbínú rẹ̀?
18
Wọ́n dàbí àkékù oko níwájú afẹ́fẹ́, àti bí ìyàngbò, tí ẹfúùfù ńlá fẹ́ lọ.
19
Ẹ̀yin wí pé, ‘Ọlọ́run to iya ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jọ fún àwọn ọmọ rẹ̀.’ Jẹ́ kí ó san án fún un, yóò sì mọ̀ ọ́n.
20
Ojú rẹ̀ yóò rí ìparun ara rẹ̀, yóò sì máa mu nínú ríru ìbínú Olódùmarè.
21
Nítorí pé àlàáfíà kí ni ó ní nínú ilé rẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀, nígbà tí a bá ké iye oṣù rẹ̀ kúrò ní agbede-méjì?
22
“Ẹnikẹ́ni le íkọ́ Ọlọ́run ní ìmọ̀? Òun ní í sáa ń ṣe ìdájọ́ ẹni ibi gíga.
23
Ẹnìkan a kú nínu pípé agbára rẹ̀, ó wà nínú ìrọra àti ìdákẹ́ pátapáta.
24
Ọpọ́n rẹ̀ kún fún omi ọmú, egungun rẹ̀ sì tutù fún ọ̀rá.
25
Ẹlòmìíràn a sì kú ninú kíkorò ọkàn rẹ̀, tí kò sì fi inú dídùn jẹun.
26
Wọ́n o dùbúlẹ̀ bákan náà nínú erùpẹ̀, kòkòrò yóò sì ṣùbò wọ́n.
27
“Kíyèsí i, èmi mọ̀ ìrò inú yín àti àrékérekè ọkàn yín láti ṣe ìlòdì sí mi.
28
Nítorí tí ẹ̀yin wí pé, ‘Níbo ní ilé ọmọ aládé, àti níbo ní àgọ́ àwọn ènìyàn búburú nì gbé wà?’
29
Ẹ̀yin kò béèrè lọ́wọ́ àwọn tí ń kọjá lọ ní ọ̀nà? Ẹ̀yin kò mọ̀ àmì wọn, pé
30
Ènìyàn búburú ní a fi pamọ́ fún ọjọ́ ìparun? A ó sì mú wọn jáde ní ọjọ́ ríru ìbínú.
31
Ta ni yóò sọ ipa ọ̀nà rẹ̀ kò ó ní ojú, ta ni yóò sì san án padà fún un ní èyí tí ó ti ṣe?
32
Síbẹ̀ a ó sì sin ín ní ọ̀nà ipò òkú, a ó sì máa ṣọ́ ibojì òkú.
33
Ògúlùtù àfonífojì yóò dùn mọ́ ọn. Gbogbo ènìyàn yóò sì máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn, bí ènìyàn àìníye ti lọ ṣíwájú rẹ̀.
34
“Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin fi ń tù mí nínú lásán, bí ò ṣepé ní ìdáhùn yín, eké kù níbẹ̀!”
← Chapter 20
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 22 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42