bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Job 37
Job 37
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 36
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 38 →
1
“Ayà sì fò mi si èyí pẹ̀lú, ó sì kúro ní ìpò rẹ̀.
2
Fetísílẹ̀! Fetísílẹ̀, kí ẹ sì gbọ́ ìró ohùn rẹ̀, àti èyí tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde wá.
3
Ó ṣe ìlànà rẹ̀ ní ìsàlẹ̀ ọ̀run gbogbo, Mọ̀nàmọ́ná rẹ̀ ni ó sì jọ̀wọ́ rẹ̀ lọ́wọ́ dé òpin ilẹ̀ ayé.
4
Lẹ́yìn mọ̀nàmọ́ná Òun kan fọ̀ ramúramù; ó sì fi ohùn ọláńlá rẹ̀ sán àrá; òhun kì yóò sì dá àrá dúró nígbà tí ó bá ń gbọ́ ohùn rẹ̀.
5
Ọlọ́run fi ohùn rẹ̀ sán àrá ní ọ̀nà ìyanu; ohùn ńláńlá ni íṣe tí àwa kò le mọ̀.
6
Nítori tí ó wí fún Sínóó pé, Ìwọ rọ̀ sílẹ̀ ayé, àti pẹ̀lú fún ọwọ́ òjò, àti fún òjò ńlá agbára rẹ̀.
7
Ó fi èdìdì di ọwọ́ gbogbo ènìyàn kí gbogbo wọn kí ó lè mọ iṣẹ́ rẹ̀ ó sì tún dá olúkúlùkù ẹ̀nìyàn dúró lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀
8
Nígbà náà ní àwọn ẹranko wọ inú ihò lọ, wọn a sì wà ni ipò wọn.
9
Láti ìhà gúsù ni ìjì àjàyíká tí jáde wá, àti òtútù láti inú afẹ́fẹ́ ti tú àwọ̀sánmọ̀ ká.
10
Nípa ẹ̀mí Ọlọ́run a fí ìdí-omi fún ni, ibú-omi á sì sún kì.
11
Pẹ̀lúpẹ̀lú ó fi omi púpọ̀ mú àwọ̀sánmọ̀ wúwo, a sì tú àwọ̀sánmọ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ká ara wọn.
12
Àwọn wọ̀nyí i káàriri nípà ìlànà rẹ̀, kí wọn kí ó lé ṣe ohunkohun tí ó pa láṣẹ fún wọn lórí ilẹ̀ ayé.
13
Ó mú àwọ̀sánmọ̀ wá, ìbá ṣẹ fún ìkìlọ̀, tàbí omi wá sí ayé láti fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn.
14
“Jóòbù, dẹtí sílẹ̀ sí èyí; dúró jẹ́ẹ́ kí o sì ro iṣẹ́ ìyanu Ọlọ́run.
15
Ìwọ mọ àkókò ìgbà tí Ọlọ́run sọ wọ́n lọ́jọ̀, tí ó sì mú ìmọ́lẹ̀ àwọ̀sánmọ̀ rẹ̀ dán?
16
Ìwọ mọ ti àwọ̀sánmọ̀ í fòó lọ, iṣẹ́ ìyanu ẹni tí ó pé ní ìmọ̀?
17
Aṣọ rẹ̀ ti máa gbóná, nígbà tí ó fi atẹ́gùn ìhà gúsù mú ayé dákẹ́.
18
Ìwọ ha ba tẹ́ pẹpẹ ojú ọ̀run, tí ó dúró sinsin, tí ó sì dàbí dígi tí ó yọ̀ dà?
19
“Kọ́ wa ní èyí tí a lè wí fún un; nítorí pé àwa kò le ílàdí ọ̀rọ̀ nítorí òkùnkùn wa.
20
A ó ha wí fún un pé, èmi fẹ́ sọ̀rọ̀? Tàbí ẹnìkan lèwí pé, ìfẹ́ mi ni pé kí a gbémi mù?
21
Ṣibẹ̀ nísinsin yìí ènìyàn kò rí oòrùn tí ń dán nínú àwọ̀sánmọ̀, ṣùgbọ́n afẹ́fẹ́ ń kọjá, a sì fẹ́ wọn mọ́.
22
Góòlù dídán ti inú ìhà àríwá jáde wá; lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni ọláńlá ẹ̀rùn ńlá.
23
Nipa ti Olódùmarè àwa kò le wádìí rẹ̀; ó ré kọjá ní ipá; nínú ìdájọ́ àtí títí bi oun kì í ba ẹ̀tọ́ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òtítọ́ jẹ́.
24
Nítorí náà ènìyàn ha máa bẹ̀rù rẹ̀; òun kì í se ojú sájú ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́n ní ayé?”
← Chapter 36
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 38 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42