bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Job 40
Job 40
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 39
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 41 →
1
OLÚWA dá Jóòbù lóhùn sí pẹ̀lú, ó sì wi pé:
2
“ẹni tí ń wá ẹ̀sùn yóò bá Olódùmarè wíjọ́ bí? Ẹni tí ń bá Ọlọ́run jiyàn jẹ́ kí ó dáhùn!”
3
Nígbà náà ni Jóòbù dá OLÚWA lóhùn wá ó sì wí pé,
4
“Kíyèsí i, èmi kò jámọ́ ohun kankan; ohun kí ni èmi ó dà? Èmi ó fi ọwọ́ le ẹnu mi.
5
Ẹ̀ẹ̀kan ní mo sọ̀rọ̀, ṣùgbọ́n èmi kò rí ìdáhùn kankan; lẹ́ẹ̀kejì ni, èmi kò sì ní sọ ọ́ mọ́.”
6
Nígbà náà ní OLÚWA sọ̀rọ̀ fún un láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé:
7
“Di àmùrè gíri ní ẹgbẹ́ rẹ, èmi ó bi ọ léèrè, kí ìwọ kí ó sì dá mi lóhùn.
8
“Ìwọ ha fẹ́ mú ìdájọ́ mi di asán? Ìwọ ó sì dá mi lẹ́bi, kí ìwọ lè ṣe olódodo
9
Ìwọ ni apá bí Ọlọ́run tàbí ìwọ lè fi ohùn sán àrá bí òun?
10
Fi ọlá ńlá àti ọlá ìtayọ rẹ̀ ṣe ara rẹ ní ọ̀ṣọ́, tí ó sì fi ògo àti títóbi ọ̀ṣọ́ bi ara ní aṣọ.
11
Mú ìrúnu ìbínú rẹ jáde; kíyèsí gbogbo ìwà ìgbéraga rẹ kí o sì rẹ̀ ẹ́ sílẹ̀
12
Wo gbogbo ìwà ìgbéraga, ènìyàn kí o sì rẹ ẹ sílẹ̀, kí o sì tẹ ènìyàn búburú mọ́lẹ̀ ní ipò wọn.
13
Sin gbogbo wọn pa pọ̀ nínú erùpẹ̀, kí o sì di ojú ìkọ̀kọ̀ wọn ní isà òkú
14
Nígbà náà ní èmi ó yàn ọ́ pé, ọwọ́ ọ̀tún ara rẹ lè gbà ọ́ là.
15
“Ǹjẹ́ nísinsìnyí kíyèsí Béhámótì tí mo dá pẹ̀lú rẹ: òun ha máa jẹ koríko bí ọ̀dá màlúù.
16
Wò o nísinsìnyí, agbára rẹ wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ, àti ipa rẹ nínú ìṣàn ìkún rẹ.
17
Òun a máa jù ìru rẹ̀ bí i igi kédarì; Isan itan rẹ̀ dijọ pọ̀.
18
Egungun rẹ̀ ní ògùsọ̀ idẹ; Egungun rẹ̀ dàbí ọ̀pá irin.
19
Òun ni olórí nínú àwọn iṣẹ́ Ọlọ́run; ṣíbẹ̀ Ẹlẹ́dàá rẹ̀ fi idà rẹ̀ lé e lọ́wọ́.
20
Nítòótọ́ òkè ńláńlá ní imu ohun jíjẹ fún un wá, níbi tí gbogbo ẹranko ìgbẹ́ máa siré ní ẹ̀gbẹ́ ibẹ̀
21
Ó dùbúlẹ̀ lábẹ́ igi lótósì, lábẹ́ èèsún àti ẹrẹ̀.
22
Igi lótósì síji wọn bò o; igi àrọ̀rọ̀ odò yí i kákiri.
23
Kíyèsí i, odò ńlá sàn jọjọ, òun kò sálọ; ó wà láìléwu bí ó bá ṣe pé odò Jọ́rdánì ti ṣàn lọ sí ẹnu rẹ̀.
24
Ẹnìkan ha lè ímú u ní ojú rẹ̀, tàbí a máa fi ọ̀kọ̀ gún imú rẹ̀?
← Chapter 39
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 41 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42