bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba 2010
/
Job 17
Job 17
Yoruba 2010
← Chapter 16
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 18 →
1
“Ọkàn mi bàjẹ́, ọjọ́ ayé mi ti dópin, ibojì sì ń dúró dè mí.
2
Dájúdájú àwọn ẹlẹ́yà yí mi káàkiri, wọ́n ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ lojukooju.
3
Fi nǹkan ẹ̀jẹ́ kan lélẹ̀ fún mi lọ́dọ̀ rẹ; ta ló wà níbẹ̀ tí yóo ṣe onídùúró fún mi?
4
Níwọ̀n ìgbà tí o ti mú ọkàn wọn yigbì sí ìmọ̀, nítorí náà, o kò ní jẹ́ kí wọ́n borí.
5
Bí ẹnìkan bá hùwà ọ̀dàlẹ̀, tí ó ṣòfófó àwọn ọ̀rẹ́, kí ó lè pín ninu ohun ìní wọn, àwọn ọmọ olúwarẹ̀ yóo jìyà.
6
O ti sọ mí di ẹni àmúpòwe láàrin àwọn eniyan, mo di ẹni tí à ń tutọ́ sí lára.
7
Ìbànújẹ́ sọ ojú mi di bàìbàì, gbogbo ẹ̀yà ara mi dàbí òjìji.
8
Èyí ya àwọn olódodo lẹ́nu, aláìlẹ́bi sì dojú kọ ẹni tí kò mọ Ọlọrun.
9
Sibẹsibẹ olódodo kò fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀, ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́ sì ń lágbára sí i.
10
Ṣugbọn ní tiyín, bí ẹ tilẹ̀ ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ, n kò ní ka ẹnikẹ́ni kún ọlọ́gbọ́n láàrin yín.
11
“Ọjọ́ ayé mi ti dópin, èrò ọkàn mi ti dàrú, àwọn ohun tí ọkàn mi ń fẹ́ sì ti di asán.
12
Wọ́n sọ òru di ọ̀sán, wọ́n ń sọ pé, ‘Ìmọ́lẹ̀ kò jìnnà sí òkùnkùn.’
13
Bí mo bá ní ìrètí pé ibojì yóo jẹ́ ilé mi, tí mo tẹ́ ibùsùn mi sinu òkùnkùn,
14
bí mo bá pe isà òkú ní baba, tí mo sì pe ìdin ní ìyá tabi arabinrin mi,
15
níbo ni ìrètí mi wá wà? Ta ló lè rí ìrètí mi?
16
Ṣé yóo lọ sí ọ̀gbun àìnísàlẹ̀ ni? Ṣé àwa mejeeji ni yóo jọ wọ inú erùpẹ̀ lọ?”
← Chapter 16
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 18 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42