bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba 2010
/
Job 32
Job 32
Yoruba 2010
← Chapter 31
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 33 →
1
Àwọn ọkunrin mẹtẹẹta náà kò dá Jobu lóhùn mọ́, nítorí pé ó jẹ́ olódodo lójú ara rẹ̀.
2
Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, ní ìdílé Ramu bá bínú sí Jobu, nítorí pé ó dá ara rẹ̀ láre dípò Ọlọrun.
3
Ó bínú sí àwọn ọ̀rẹ́ Jobu mẹtẹẹta pẹlu, nítorí pé wọn kò mọ èsì tí wọ́n lè fún Jobu mọ́, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n dá a lẹ́bi.
4
Elihu ti fẹ́ bá Jobu sọ̀rọ̀ tẹ́lẹ̀, ṣugbọn ó dákẹ́, nítorí àwọn àgbà tí wọ́n jù ú lọ ni wọ́n ń sọ̀rọ̀.
5
Ṣugbọn nígbà tí Elihu rí i pé àwọn mẹtẹẹta kò lè fún Jobu lésì mọ́, inú bí i.
6
Ó ní, “Àgbàlagbà ni yín, ọmọde sì ni mí, nítorí náà ni ojú fi ń tì mí, tí ẹ̀rù sì ń bà mí láti sọ èrò ọkàn mi.
7
Mo ní kí ẹ̀yin àgbà sọ̀rọ̀, kí ọ̀rọ̀ yín sì fa ọgbọ́n yọ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ orí yín.
8
Ṣugbọn ẹ̀mí tí ó wà ninu eniyan, tíí ṣe èémí Olodumare, ni ó ń fún eniyan ní ìmọ̀.
9
Kì í ṣe àwọn àgbà nìkan ni wọ́n gbọ́n, tabi pé arúgbó nìkan ni ó mọ òye ohun tó tọ́, tó yẹ.
10
Nítorí náà, ‘Ẹ fetí sílẹ̀, kí èmi náà lè sọ èrò ọkàn mi.’
11
“Mo farabalẹ̀ nígbà tí ẹ̀yin ń sọ̀rọ̀, mo fetí sí ọ̀rọ̀ ọgbọ́n yín, nígbà tí ẹ̀ ń ronú ohun tí ẹ fẹ́ sọ,
12
Mo farabalẹ̀ fun yín, ṣugbọn kò sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí ó lè ko Jobu lójú, kí ó sì fi àṣìṣe rẹ̀ hàn án, tabi kí ó fún un lésì àwọn àwíjàre rẹ̀.
13
Ẹ ṣọ́ra, kí ẹ má baà wí pé, ‘A ti di ọlọ́gbọ́n, Ọlọrun ló lè ṣe ìdájọ́ rẹ̀, kì í ṣe eniyan.’
14
Èmi kọ́ ni Jobu ń bá wí, ẹ̀yin ni, n kò sì ní dá a lóhùn bí ẹ ṣe dá a lóhùn.
15
“Ọkàn wọn dàrú, wọn kò sì lè fèsì mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní ohun kan láti sọ.
16
Ṣé kí n dúró, nítorí pé wọ́n dúró láìfèsì?
17
Èmi náà óo fèsì lé e, n óo sì sọ èrò ọkàn tèmi.
18
Mo ní ọ̀rọ̀ pupọ láti sọ, Ṣugbọn ẹ̀mí tí ó wà ninu mi ló ń kó mi ní ìjánu.
19
Ọ̀rọ̀ kún inú mi bí ọtí inú ìgò, ó fẹ́ ru síta bí ọtí inú ìgò aláwọ.
20
Mo níláti sọ̀rọ̀ kí ara lè rọ̀ mí, mo gbọdọ̀ la ẹnu mi kí n sì dáhùn.
21
N kò ní ṣe ojuṣaaju ẹnikẹ́ni, bẹ́ẹ̀ ni n kò sì ní gbèjà eniyan.
22
Nítorí n kò mọ bí wọ́n ṣe ń pọ́n eniyan, kí Ẹlẹ́dàá mi má baà pa mí run ní kíá.
← Chapter 31
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 32
Chapter 33
Chapter 34
Chapter 35
Chapter 36
Chapter 37
Chapter 38
Chapter 39
Chapter 40
Chapter 41
Chapter 42
Chapter 33 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42