bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Yoruba
/
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
/
Proverbs 2
Proverbs 2
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
← Chapter 1
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 3 →
1
Ọmọ mi, bí ìwọ bá gba ọ̀rọ̀ mi, tí ìwọ sì pa òfin mi mọ́ sí inú rẹ,
2
tí o tẹ́ etí rẹ sílẹ̀ sí ọgbọ́n tí o sì fi ọkàn rẹ sí òye,
3
bí ìwọ sì pè fún ojú inú rẹ ríran tí o sì kígbe sókè fún òye
4
bí ìwọ bá wá ṣàfẹ́rì rẹ̀ bí i fàdákà tí o sì wa kiri bí i fún ohun iyebíye tó fara sin.
5
Nígbà náà ni òye ẹ̀rù OLÚWA yóò yé ọ, tí ó sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.
6
Nítorí OLÚWA ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n, láti ẹnu rẹ̀ sì ni ìmọ̀ àti òye ti ń wá
7
Ó to ìgbàlà fún àwọn olódodo, Òun ni aṣà fún àwọn tí ń rìn déédé,
8
ó pa ipa ọ̀nà ìdájọ́ mọ́ Ó sì ń pa ọ̀nà àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ mọ́.
9
Nígbà náà ni òye ohun tí ó tọ̀nà tí ó sì dára, tí ó dára yóò yẹ́ ọ—gbogbo ọ̀nà dídara.
10
Nítorí ọgbọ́n yóò wọ inú ọkàn rẹ ìmọ̀ yóò sì jẹ́ ìtura fún ọkàn rẹ
11
Ara (ikú) sísọ ni yóò dáàbò bò ọ Òye yóò sì pa ọ́ mọ́.
12
Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú, lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn tí ọrọ̀ ọ wọn jẹ́ àyídáyidà,
13
tí ó kúrò ní ọ̀nà tààrà láti rìn ní ọ̀nà tí ó ṣókùnkùn,
14
tí ó ní inú dídùn sí ibi ṣíṣe tí ó sì ń yayọ̀ nínú àyídáyidà ibi,
15
ọ̀nà àwọn tí ó ṣe pálapàla tí wọ́n sì jẹ́ alérekérekè ní ọ̀nà wọn.
16
Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àgbèrè Obìnrin lọ́wọ́ aya oníwàkúwà àti àwọn ọ̀rọ̀ ìtànjẹ rẹ̀,
17
tí ó ti fi ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀ tí ó sì gbàgbé májẹ̀mú tí ó ti dá níwájú Ọlọ́run.
18
Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú ọ̀nà rẹ̀ sì lọ sí ibi ẹ̀mí àwọn òkú.
19
Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà tàbí tí ó rí ipa ọ̀nà ìyè.
20
Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere kí o sì rìn ní ọ̀nà àwọn Olódodo
21
Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náà àwọn aláìlẹ́gàn sì ni yóò máa wà lórí rẹ̀
22
ṣùgbọ́n a ó ké ènìyàn búburú kúrò lórí ilẹ̀ náà a ó sì ya àwọn aláìsòótọ́ kúrò lórí rẹ̀.
← Chapter 1
Jump to:
Chapter 1
Chapter 2
Chapter 3
Chapter 4
Chapter 5
Chapter 6
Chapter 7
Chapter 8
Chapter 9
Chapter 10
Chapter 11
Chapter 12
Chapter 13
Chapter 14
Chapter 15
Chapter 16
Chapter 17
Chapter 18
Chapter 19
Chapter 20
Chapter 21
Chapter 22
Chapter 23
Chapter 24
Chapter 25
Chapter 26
Chapter 27
Chapter 28
Chapter 29
Chapter 30
Chapter 31
Chapter 3 →
All chapters:
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31